Ojo nla ti opo eeyan ko ni i gbagbe lanaa, ojo kin in ni osu kewaa, odun yii. Ojo naa ni Oloye Yetunde Babajide, oludari ileese YEFADOT Group of companies sayeye ojoobi e.
Inu gbongan nla Gabovic to wa ni Ojodu-Berger layeye ohun ti waye. Beeyan ba wo inu gbongan yii, ko digba ti won ba so fun eeyan ko too mo pe eni nla lo n se ojoobi lojo naa, se ni gbogbo inu gbongan naa ku fun awon eeyan Pataki, awon omowe, awon oniseowo, awon onisowo, awon agbe atawon onileefowopamo.
Lara ohun to sele lojo naa ni idanilekoo nipa bi eeyan se le di olowo, idanilekoo nipa ilera wa. Bee lawon agbalagba kan naa janfaani ebun lo sile lojo yii.
Gbajugbaja osere tiara nni, Madam Kofo Onigele Ara lo dari ayeye naa.
Ninu oro Oloye Yetunde to run je Iyalode ilu Ojodu lo ti so pe pun dupe lowo Olorun pe oun tun le odun kan si I loke eepe. Bee lo fi kun oro e pe ko si ohun to je oun login ju bi igbe aye yoo se rorun fun teru-tomo lo lorileede yii.
No comments:
Post a Comment