IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 15 August 2021

Alaaja Wulemotu di osi iya Adinni ijo Ansar-u-deen


Ilu Ijebu Owo nipinle Ondo mi titi lojo satide to koja nibi ti Alaaja Adenike Wulemotu ti di Osi iya Adinni ninu ijo Ansar-u-deen ninu ilu naa.

Awon Sheik ijo yii lo fori kori lati fi Oye nla yii ta iya naa lore latari awon ise takuntakun ti iya naa ti se ninu ijo Ansar-u-deen,Alaaja Wulemotu je oluferan esin isilaamu ti ko si ko iyan awon elesin isilaamu kere rara.

Oba Orin Saheed Osupa lo dalubole lojo naa.

No comments:

Post a Comment

Adbox