IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 4 June 2021

Omooba Taiwo Saliu Oniro Alebiosu La n fe gege bii Olupo tilu Ajase-Ipo


Awon eeyan ilu Ajase-Ipo, nipinle Kwara ti so pe Omooba Taiwo Saliu Oniro Alebiosu lawon n fe gege bii oba tuntun niluu naa.

Awon to soro yii so pe ko si elomi-in to ye nipo yii ju Omooba Taiwo Oniro lo. Won ni omowe, to ti gbe loke-okun fun aimoye odun, to fi owo ti Olorun fun un tu ilu se ni Omooba Taiwo Oniro. Won lo Awon loju doba pe to ba dori ite Awon baba nla re, opo ilosiwaju ati idagbasoke ni yoo my ba ilu.
Won waa ro awon afobaje pe eni to ye loye ni ki won gbe sori apere to sofo yii.


No comments:

Post a Comment

Adbox