IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 2 May 2021

Emi ati ọrẹ mi lati ilẹ okere, to tun jẹ akẹkọọ mi



Latọwọ Kong Tao

Ni nnkan bii ọdun meloo kan ṣẹyin, awọn ọpọlọpọ oṣiṣẹ lati awọn ileeṣẹ China ti lọ si ilu okeere lati darapọ mọ awọn ọja okeere.Wọn fi ilera ile wọn silẹ lati kọ aala fun gbogbo eeyan pẹlu iyasọtọ aláìmọtara-ẹni-nìkan lati ṣeto ohun to dara ati ibatan to lagbara pẹlu awọn ọrẹ okere.

E Jẹ ki a wo awọn irepo to sunmọ nipasẹ oluko ati ọrẹ ti won ti ṣiṣẹ pọ ni Afrika.

Orukọ mi ni Kong Tao, bi a se ri ninu aworan to wa loke, emi ni ọkunrin to wa ni apa osi pelu Iyaafin Issah Fatimah Abiọla lapa ọtun jẹ ọrẹ mi ati oṣiṣẹ ileeṣẹ CCECC Naijiria , ti orukọ rẹ lede China n je Bai yang. Lọdun 2008, a yan an gege bii oluranlọwọ ọfiisi nipasẹ CCECC  fun ẹka track laying  pẹlu ṣiṣi iṣẹ-ọna oju irin ilu Abuja si Kaduna ati idawọle ibi-irekọja ọpọ eniyan ti Abuja, Mo mu imọran wa pe o to akoko fun un lati gba ipo tuntun kan. Lẹyin gbogbo igbiyanju, Abiola di obirin akoko awakọ oju irin ninu itan Naijiria.

CCECC a ma a sọ awọn ipa nla si ikẹkọọ ti oṣiṣẹ agbegbe nigba gbogbo bo ti to ati bo ti yẹ. A yan mi gẹgẹ bii olukọ ati alamoojuto Baiyang, lati kọ ọ ni ede, eyi lo mu mi ra diẹ ninu awọn iwe ikọnil ede ile China ati ibẹrẹ ikẹkọọ lati ikinni bii hello Ni hao “. Bai Yang ni idẹkun ninu aṣa ati ede Ilu China, iṣẹ takuntakun to se fun ilọsiwaju jẹ iyalẹnu gidi fun mi.

Gẹgẹ bi alakọbẹrẹ ninu iṣẹ ati itoju ọkọ oju irin, Bai Yang ko ni oye pupọ ni gbigba imọ nipa awọn ohun eelo ọkọ oju-irin ati awọn ero ati ifihan agbara irekọja. Mo nigbagbogbọ fi idojukọ mi si aaye yii lakoko ikẹkọọ ati fun awọn apẹẹrẹ igba lati tàn wọn loju.

Mo ri i pe awọn ọmọ ileewe Naijiria jẹ ọlọgbọn pupọ, paapaa ninu iṣẹ. Wọn si tun ni oye awọn ilana ṣiṣe. Nigba kan ti mo ba n ronu ohun ti mo fẹẹ  sọ nipa bawo ni lati ṣalaye awọn aaye imọ diẹ nipa ikede ede Gẹẹsi, wọn ti loye ohun ti mo fẹẹ sọ. Dajudaju, Bai Yang ni akẹkọọ to yara ju lo ninu awọn ti Mo ti pade tẹlẹ. Ki i ṣe ọlọgbọn nikan, ṣugbọn o jẹ alaapọn pupọ ati oṣiṣẹ to dangajia.

Lakooko ayẹyẹ ṣiṣi ti ‘Rail Transit Project’ ti Abuja to waye ọjọ kejila, oṣu keje  ọdun 2018, Bai Yang, gẹgẹ bii awakọ oju- irin obirin akọkọ ni Nigeria, jabọ fun Aare Muhammadu Buhari ninu gbigbe, ti ọjọ naa si tun  jẹ ọjọọbi rẹ. Gẹgẹ bii oluko ati ọrẹ rẹ, inu mi dun gan-an fun un ni.

Itan ti “Akọkọ Obirin Awakọ Locomotive” ti tan kaakiri ni Naijiria, Bai Yang ti di olokiki tuntun lori ẹrọ ayelujara ni Naijiia. Gẹgẹ bi ọrẹ ẹ lati oke- okun, Mo pẹlu rẹ ni ọpọlọpọ awọn ibere ijomitoro-ọrọ nipasẹ awọn oniroyin ajeji. Gbogbo igba ni Bai Yang dupe pupọ si ijọba Ilu China ati CCECC. O sọ pe “One belt one road Initiative” ti mu awọn aye ati iyato nla wa si Naijiria, ati pe kikọ awọn oju-irin tuntun ni Naijiria ti mu ayipada ba ọna ti awọn eniyan n rin ati yika olu ilu ati awọn agbegbe ati igbesi aye rẹ.

 

 

Ni ọjọ kọkanla,  oṣu kẹjọ ọdun 2020, eto iroyin CCTV “Minister Talk” pe mi ati Bai Yang gẹgẹ bii awọn alejo pataki. A sọrọ nipa ipa nla ti awọn ileeṣẹ China ko nipa eto  ikọle loke-okun ati pe mo ṣalaye ọpẹ tọla mi si CRCC fun ipese mi pẹlu awọn iru ẹrọ nla ati awọn aaye ati si gbogbo awọn ọrẹ Afrika. Ore ti a fipinlẹ ni oke okun yoo wa titi lailai. Bai Yang sọ ninu ifọrọwanilẹnuwo pe oun ko le mu ala ati erongba oun  la ti di awakọ oju irin sẹ ti ko ba si ti CCECC ati awọn ọrẹ rẹ lati ilẹ China. Pẹlu, O si fi ifẹ ijinlẹ han fun China ati awọn ileeṣẹ CCECC.

Mo kopa ninu iṣẹ ati ṣiṣẹ ti awọn oju-irin, paapaa julọ ni Naijiria, pataki julo ni ẹka Abuja-Kaduna Railway ati Abuja Rail Mass Transit Project. Pẹlu itankale gbogbo orilẹ-ede ti itan- “Awakọ Oju irin Obirin Akọkọ ti mo funra kọ gege bii olukọ to ni ifojusi lati gbogbo awọn ayika ni Naijiria. Lọdun 2019, won fun mi ni akọle-oye ti "WAKILIN AYYUKA" latọwọ Emir ti Jiwa, adari awọn ofin ibile agbegbe. Emi ko gba bii ọlá ti ara mi; dipo, ki ojẹ ẹsan fun gbogbo awọn eniyan Ilu China ti wọn tẹra mọ si awọn ifiweranṣẹ oke okun.

Ore ko mọ awọn aala.

Ọrẹ laarin Bai Yang ati emi jẹ apẹrẹ  imusẹ ti “Belt and Road Initiative”. Ni ibamu si awọn ọdun awọn iriri wọnyi ni Afrika, Mo ni iriri gan-an to ni i se pẹlu “ṣiṣẹ pọ fun idagbasoke to wọpọ, ti o jẹ

” iran ti awọn eeyan China ati awọn eeyan Afirika

 

No comments:

Post a Comment

Adbox