IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 7 April 2021

Kemi Wonder, Gbajugbaja olorin emi gbe rekoodu tuntun jade- Iyin re lo pe e


Okan gboogi ninu awon omo orileede yii ti won n se daadaa nidii ise orin kiko loke-okun ni Efanjeliisi Kemi Ayade tawon eeyan mo si Kemi Wonder.

Iroyin  ayo to te wa lowo bayii ni pe obinrin naa ti pari ise lori rekoodu e tuntun to pe ni 'Iyin re'. Rekoodu naa la gbo pe yoo gori igba laipe yii.

Lasiko to n ba wa soro, Kemi Wonder ni gbogbo ibi ti won ba ti n ta ojulowo rekoodu lawon eeyan yoo ti ri rekoodu Iyin re ra. Obinrin yii wa a ro gbogbo awon omoleyin Jesu lati ra rekoodu yii to ba ti jade. O ni awon orin ope, Orin Iyin ati orin ile ologo lawon eeyan yoo gbo ninu rekoodu naa.

Yato si pe o n korin, gbajumo alase ti won n pe ni caterer lobinrin yii.

No comments:

Post a Comment

Adbox