Ojo kejidinlogbon, osu keji, odun ti a wa yii ni gbajumo aafaa akomonikewu, Fadeelat Sheikh Abdulganiy Iyanda Ajibade Akewusola yoo sayeye wolimot fawon akekoo won.
Ileewe to won n ko nipa ede larubawa ati eko islammu ti oruko re n je 'Nihmatullahi Arabic And Islamic Training Center' to wa ni Okoro-Ojuroko, Idiroko, ipinle Ogun lo fee ko awon akekoojade tuntun jade.
Oniwaasi ojo naa ni Fadeelat Sheik Doctor Sulaiman Farooq Onikijipa ni oniwaasi lojo naa. Awon eeyan pataki lawujo ni won n reti nibi ayeye naa.
No comments:
Post a Comment