Ninu oro e, Arabanbi Akoko, ni inu oun dun pe oun lo odun kan lori oye gege bii Mayegun ile Yoruba.
Osere nla yii fi kun oro e pe asiko to ye ki gbogbo eeyan lagbaaye kun fun adura ki alaafia le joba kari aye.
O ni pelu bi a ti se wo inu odun tuntun yii, o ye ki gbogbo wa pata kun fun adura ki ilosiwaju ati idagbasoke le e ba gbogbo wa.
No comments:
Post a Comment