IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 13 January 2021

O ma se o: Korona Fairoosi tun pa Dokita Bolu Akin-Olugbade

Arun asekupani to n je korona fairoosi tun se ose nla, baba olowo nla nni, Dokita Bolu Akin-Olugbade ni arun naa tun mu lo bayii.
Ipago awon to lugbadi arun korona to wa niluu Eko ni arun okunrin olowo nla ohun dake si.

Gbogbo awon eeyan to sunmo okunrin yii ni won sedaro e, won ni eeyan pataki ti lo lawujo.

No comments:

Post a Comment

Adbox