IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 13 January 2021

Ninu Odun Tuntun, Funmi Awelewa pate oyan sita gbangba

Gbogbo awon eeyan to ri foto oyan e ti gbajugbaja osere tiata Yoruba, Funmi Awelewa tawon ololufe e mo si Morili gbe sita sori ero ayelujara ni won n pariwo pe ki ree Eledumare, won ni omun ohun po daadaa.

Se loju awon okunrin ran mo kinni ohun ti won beeere lowo Morili se o fee pa awon ni. Ko buru, ko baje, osere naa fi oore Olorun ran ninu aye e ni.

No comments:

Post a Comment

Adbox