Ona ara, ona ayo gba a ni gbajugbaja osere ti oruko re n je Biodun Sofuyi Okeowo, sugbon ti gbogbo aye mo si Omo Borty fi here odun tuntun yii.
Moto kan lobinrin naa sowo e, sugbon nigba ti won yoo gbe moto e wa fun un, moto boginni meji nileese Unique motor ti obinrin naa ra moto e lowo won gbe wa a fun un, won ni enikan ti fi moto mi-in ta a lore.
Alaye ti osere nla yii se ni pe oriire nla loun fi here odun tuntun yii.
Gbogbo awon ololufe e ti won ri awon oriire nla yii ni won ki ku oriire, won ni emi re yoo lo awon moto nla yii.
No comments:
Post a Comment