Osu kerin, odun to koja lo ye ki ayeye nla ti agba-oje olorin Islam, Alaaji Wasiu Kayode As-Sidik fee se ti waye, sugbon arun korona fairoosi to gbalu lo je ki won sun ayeye ohun siwaju si ojo kejidinlogbon, osu, keta odun yii.
Ayẹyẹ ohun ni ọgbọn ọdun to ti n kọrin, fifun awọn eeyan lami-ẹyẹ ati ifilọlẹ fidio orin rẹ to pe ni 'Ẹ ṣamin'
Gbongan Times Square Event Centre to wa ni Adeniyi Jones, ni Ikeja, layeye naa yoo ti waye.
Baba ojo naa ni agbenuso ile igbimo asofin Eko, Onarebu Mudatheer Ajayi Obasa, nigba ti awon iya ojo naa yoo je Alhaja Shuqurah Modupeola Shine Shine ati Alhaja Rahmatallah Alausa.
Awon oba alaye ojo naa ni Oba Abdulfattah Akorede Akamo Olu tiluu Itori ati Oba Muhammad Saheed Ifalohun Odusanya Onidioke tiluu Igbesa.
Awon eeyan pataki lawujo, pelu awon osere tiata atawon olorin ni won n reti nibi ayeye naa
‘Awon ti yoo dari ayeye naa ni, Okele ati Aponle Anobi. As-Sideeq, ro gbogbo awon ololufe e lati fi.
Leesi egberun lona ogbon naira ati Ankara egberun marun-un lawon eeyan too fi wole sibi ayeye yii. Enikeni to ba fee ra aso iwole yii, e pe awon nomba yii:08098025527, 08029480566 ati 08093715900
No comments:
Post a Comment