IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 12 September 2020

Gongo so lojo ti ileese 'Magazine Giraffe International' Seto Ami-Eye Nla Fun Eso Alaabo 'Onyabo' niluu Ikorodu



Ojo nla lojo Eti, Fraide to koja je fun awon eso alaabo to n gbogunti iwa ibaje lawujo, ti won n je Onyabo, idi ni pe ojo naa ileese Giraffe International Magazine ti Alagba Akin Sokoya je oludasile e seto Ami-eye nla fun awon eekan kan laarin awon eso alaabo yii.

Ami-eye yii ti won fi sori awon eso alaabo lorile-ede yii lo je alakooko iru e, eso alaabo Onyabo ni won koko fun Lani-eye yii. Bamubamu lawon oga eso yii atawon tooku ninu iko yii kun gbongan 'Recreation Center' to wa ni Ita-Elewa niluu Ikorodu ti ami-eye naa ti waye.

Ninu oro e, Alagba Sokoya, so pe oun dupe lowo gbogbo awon eso alaabo Onyabo fun ipa nla ti won n ko fun gbigbogunt iwa ibaje ati iwa odaran lawujo. O ni nitori ipa ribiribi ti won n ko lawon se bere ami-eye naa lodo won. O ni lasiko ti Onyabo wo ilu Ikorodu niwa odaran lo sile patapata

No comments:

Post a Comment

Adbox