Eto kan to gbe kale fawon agba yii lo pe orukọ re ni 'Foluke Salako's PARA Africa 2019 Nolly Veterans Gala Night
. Gbogbo awọn agba oje onitiata ti won wa nibi eto yii to waye ni gbongan Anchor Event Centre ni won gba owo nla ati ami-eye lo sile,bee ni won gbadun ara won daadaa lojo yii. Gbogbo awon eeyan to wa nibe lojo naa ni won sadura fun Foluke ati oko e, Kayode Salako, won ni ohun to ye kijoba se losere nla yii se fawon agbalagba yii.
No comments:
Post a Comment