Okan pataki ninu awon ojise Olorun ti oba oke n lo lati gba awon eeyan kale lowo
ajaga esu atawon iranse e ni Prophetes Kehinde Osoba tawon eeyan mo si Eritoosin,
mama yii ni oludasile ijo kerubu Apata Ayeraye to wa ni Omitooro niluu Eko.
Opo
ise iyanu ni Olorun ti gba owo iranse e yii se,lara e ni eni to n wa omo fun
opolopo odun, eni to ni aisan olojo pipe, eyi to waye lojo laipe yii leni
to lu magun lara obinrinto je pe die lo ku bayii ko dero orun,sugbon ti Olorun
pada da emi re pada latowo iranse e yii.
Fun
ebe adura ati itonisona, e pe Prophetes Kehide Osoba sori nomba yii:080233365539
No comments:
Post a Comment