IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 22 December 2019

JAGUNJA ISALE FEE SAYEYE OPIN ODUN, ONIKOBO 2019 NI WON PE E


Awon osere ti yoo da awon eeyan lara ya lojo naa ni: Alaaja Azeezat Otibiya, Alaaji Azeez Ajobiewe, Queen Madiva, Iya Mufu, Ungly Boy ati Doctor J. Alejo pataki ojo naa ni gbajugbaja olorin fuji, Alaaji Abolaji Isiaka Ajani Easy Kabaka. Ninu oro awon eleto ayeye yii ni won ti so pe aabo to peye yoo wa fun gbogbo awon eeyan to ba wa sibi ayeye yii. 

No comments:

Post a Comment

Adbox