IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 21 December 2019

Gbajugbaja olorin ẹmi, Mega 99, fi rẹkọọdu 'Prayer Point' gbadura fawọn ololufẹ ẹ

Ko si orin kan tawọn ọmọlẹyin Jesu n gbọ bayii to ju rẹkọọdu adura ti ilu mọ ọn ka olorin ẹmi, Ọmọọba Abel Dosunmu ti gbogbo aye mọ si Mega 99 ṣẹṣẹ gbe jade lọ, rẹkọọdu naa to pe ni 'Prayer Points' lawọn eeyan fi jẹgbadun aye wọn bayii.

Ọpọlọpọ orin adura, orin idande ati imisi nla lo ku inu rẹkọọdu naa bamubamu. Gbogbo ibi ti wọn ba ti n ta ojulowo awo orin lawọn eeyan yoo ti ri rẹkọọdu ọhun ra. 



No comments:

Post a Comment

Adbox