IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 6 November 2019

OPE O: REKOODU TUNTUN MEGA 99, 'PRAYER POINT' TI JADE

Iroyin ayo to te wa lowo bayii ni pe rekoodu oloodun ti gbajugbaja olorin emin ati juju nni, Omooba Abel Dosunmu ti gbogbo aye mo si Mega 99 ti jade.



Rekoodu yii 'Prayer Point' to sese jade ni yoo je eleekefa ti ilu mo on ka olorin omo bibi ilu Ilaro naa yoo gbe jade. A gbo pe orisirisii orin adura ati ebe si Olorun lo wa ninu orin yii, orin ti gbogbo eniyan gbodo ni nile ni.

No comments:

Post a Comment

Adbox