Nibi ami-eye 'OYA AWARD' to maa waye lodoodun ni won ti fun Dele Gold tawon ololufe e tun maa n pe ni Gbogbo Eekun ni ami-eye nla ohun.
Saaju ki osere nla yii too gba awoodu yii lo ti koko forin aladun da awon eeyan lara ya, ti gbogbo awon eeyan nla nla to wa nibe kan saara si i pe olorin ti ori re pe daadaa lokunrin naa.
No comments:
Post a Comment