Bamubamu lawon eeyan kun ibi ayeye yii, ti awon eeyan si jeun daadaa, won mu,won si tun di lo sile.
Akeko-jade ileewe girama Imoye High School, Lagos State Polytechnic ati Lagos State University ni Moruf, imo nipa oro aje ati isakoso okowo lo se jade, bee lo tun gba awon iwe eri mi-in lorile-ede yii ati loke okun.
Ojutole ki baba olomo ati iya ikoko ku oriire, Olorun yoo wo omo naa lawoye.
No comments:
Post a Comment