IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 23 November 2019

O GA JU, ALFA LAST BORN DE LATI KAOLA, NI OTUNBA MUTIU BADMUS BA GBA AMERIKA lo

Nnkan ayo lo n sele lowolowo bayii nileese to ma n ko awon eeyan lo si Mekka ati Umrah, AL-hatyq Travel and Tours Limited, peluu bi oga igbokegbodo ileese naa, Alfa Semiu Lastborn se bale gude lati ilu Kaola to lo fun ayeye ojoobi Anobi  ti oga agba ileese yii, Otunba Mutiu Wale Badmus ti gbogbo aye mo si Wale Ticket se gba orile-ede Amerika lo.

Ojutole gbadura pe layo ati lalaafia ni Otunba yoo de.

No comments:

Post a Comment

Adbox