Bi e se n ka iroyin yii, ilu London, lodo Iya Sali lohun-un ni okan pataki ninu awon gbajumo olorin emi lorile-de yii, Efanjeliisi Bayo Tanimojo tawon ololufe e mo si Bayo Emerald wa bayii, nibi to ti n forin da awon ololufe e lara ya.Gege bi Ojutole se gbo, ojo meloo kan seyin lokunrin naa fi Naijiria sile, to ti bale gude si London, to si ti n fi orin emi gidi da awon ololufe e lara ya. Awon re
koodu ti okunrin naa ti gbe jade tele ni: Pariwo Ayo ati Step to Glory.


No comments:
Post a Comment