

Gege bi Ojutole se gbo, ayeye ohun ni: Ebunlorin
Day, ifilole rekodu tuntun, ami-eye ati Abode Meka. Ile-Igbafe 'Classic Arena Hotel and Suites', to wa ni Bakery Bus-stop, nitosi AIT Road, ni Kola, Alagbado, layeye nla ohun yoo ti waye.
Gbajugbaja olorin fuji nni, Alaaji Wasiu Alabi Pasuma Oga nla ni yoo saaju awon irawo olorin ti yoo forin aladun da awon eeyan lara ya lojo naa. Ankara oni egberun marun-un naira lawon eeyan yoo fi wole sibi ayeye yii.
No comments:
Post a Comment