IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 14 August 2019

OPE O, TOYIN ABRAHAM, OSERE TIATA YORUBA BIMO OKUNRIN S'AMERIKA, ADEDIWURA NAA DIYAWO OLORUKA

Ohun ayo nla meji lo sele lagbo awon osere tiata Yoruba loni-in, Toyin Abraham lo bimo okunrin fun oko e, Kolawole Ajewole sorile-ede Amerika, bee ni Adediwura Adesegha naa diyawo oloruka leyin odun kerinla to ko okunrin to bimo fun sile.

Gege bi a se gbo, aaro oni ni Toyin bimo, nigba ti Adediwura segbeyawo alarede losan anaa. Ohun to sele ni pe foto igbeyawo Toyin ati Kolawole lo koko gori ero ayelujara laaro oni-in, tawon eeyan si ti n ki oun ati oko e ku oriire, sugbon nigba ti yoo fi di irole iroyin ayo mi-in tun ti gbalu pe Toyin bimo okunrin si Amerika.

Ni ti Adediwura, bonkele lo se igbeyawo alarede pelu ololufe e, tawon osere egbe naa si ti ki


oun naa ku oriire.

Loro kan, awon ololufe Toyin ti so pe Olansile Abiodun lawon yoo so omo naa.

No comments:

Post a Comment

Adbox