Ojutole ba Oluomo Kutonu dupe lowo Olorun fun oore ayo yii, Olorun yoo wo omo naa lawoye, yoo soriire, yoo lalubarika
Inu idunnu ati ayo nla ni gbajugbaja aafaa tawon eeyan feran daadaa nni, Alaaji Babatunde Saheed, ti gbogbo aye mo si Oluomo Kutonu wa bayii, ko si ohun to fa ayo nla yii ju omokunrin lantilanti ti iyawo e sese bi lo. Aaro anaa, niyawo Oluomo bimo siluu Kutonu, Ojutole gbo pe daadaa niya atomo wa, bee ni ko si ohun to se baba omo, a ti gbo ohun iya,a gbo tomo, a si tun gbo ti baba naa.
Ojutole ba Oluomo Kutonu dupe lowo Olorun fun oore ayo yii, Olorun yoo wo omo naa lawoye, yoo soriire, yoo lalubarika
Ojutole ba Oluomo Kutonu dupe lowo Olorun fun oore ayo yii, Olorun yoo wo omo naa lawoye, yoo soriire, yoo lalubarika
No comments:
Post a Comment