IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 14 August 2019

ONI LOJOOBI OLORI BUKOLA OLUDELE, E JE KA BA EEYAN WA DAADAA DUPE LOWO OLORUN

Oni layeye ojoobi eeyan wa daadaa, Olori Olubukola Oludele, olori loode ore wa, Otunba Kunle Oludele ti gbogbo aye mo si Otunba  Jesu, gbogbo  wa pata la ki i ku oriire. Adura wa fun omo olojoobi ni pe ko se opo odun laye ninu ola, owo, alubarika ati igbega repete.

No comments:

Post a Comment

Adbox