Nnkan ayo kan ti sele nipinle Ogun bayii, anfaani nla lo je fun gbogbo omo jayejaye, awon omo alafe, awon to fee sayeye atawon to n wa ibi igbadun ti ko legbe. Ko si ohun meji ti a n so to ju ile itura Olu's Guest House and Event Centre lo. Gbogbo awon yaara wa lo da bii aafin oba pelu ero amule tutu to duro wamuwamu jenerato wa ki i ku pelu intaneeti ofe ti yoo je ko mo gbogbo ohun to n lo kari aye, ile igbadun oti ati ounje aladun wa ko lafiwe, anfaani wa fun eni to ba fee fo aso won ti yoo mo tonitoni.
Bee ni gbongan wa gba ero fun gbogbo ayeye ti e ba fee se.
Iwo naa de odo wa loni-in ni Igbesa Itegun Road, ipinle Ogun iwo naa yoo ri pe ile itura wa ko ni elegbe ni gbogbo ile Yoruba.
E pe wa sori nomba yii:08120935906 tabi ki e ba wa soro lori maili wa: olusguesthouseandevent@gmail.com
No comments:
Post a Comment