Ojise Olorun alaaye to tun je eleyinju aanu ti gbogbo aye n fe, Mama Refurendi Esther Abimbola Ajayi ti so asiiri idi to n se fowo ti Olorun saanu gbogbo eeyan.
Mama yii tawon eeyan tun mo si Iya Adura so pe oun naa ti wa nipo a ini ri , nitori lawon se da ajo kan to n ran awon eeyan lowo tawon pe oruko re ni Esther Ajayi Foundation sile.
O ṣalaye pe niwọn igba ti iwadii awọn ba ti jẹ ootọ pe eeyan kan nilo iranwọ, awọn maa n tete ṣe e fun wọn.
Mama ni "Awọn eeyan maa n san idamẹwaa to wuwo gan-an fun mi, iyẹn lemi naa ṣe n ribi ṣ'oore fawon to ku die kaato fun".
Iya Esther ni ẹni ti o ba n gba idamẹwaa ti ko ṣe ore tabi, ṣaanu, ki a fi silẹ sọwọ Ọlọrun. O ni "ṣugbọn bibeli sọ pe ka mu idamẹwaa wa, emi naa si n san temi".
E o ranti pe ogoro awon eeyan ni won janfaani olowo nla latowo mama alaaa
God will continue to be with us all
ReplyDelete