IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 30 July 2019

GONGO SO LOJO TAWON EBI GBAJUGBAJA OLORIN, YINKA SABEWO SAAFIN ONIPOKIA TUNTUN, OBA YISA OLANIYAN





Ojo nla lojo Aiku, Sannde, to koja yii, ojo naa lawon ebi gbajugbaja olorin to fi orile-ede Amerika sebugbe, Yinka Ryhymz, sabewo saafin Onipokia ti won sese yan, Oba Yisa  Olaniyan Adeniyi Adelakun Oshigin Keji Onipokia tile Ipokia. Mama Yinka, Arabinrin Bolanle Onigbanjo, lo saaju awon ebi yooku lo saafin Oba Alaye tuntun yii.

Tayo-tayo loba tuntun yii fi gba awon eeyan yii lalejo ni Igbebi to wa lati bii ose meloo kan seyin. Ninu oro oba nla yii lo ti dupe lowo awon alejo e yii, bee lo pase ki won sure fun Yinka Rtymz. 

Bakan naa lo sapejuwe osere nla yii bi ojulowo omo Yoruba to n gbe orile-ede yii ga loke-okun.




No comments:

Post a Comment

Adbox