IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 7 July 2019

ERO REPETE NIBI ADURA OJO KEJO MAMA IYA-N-GHANA, AWON OLORIN ISLAM SE BEBE LOJO NAA

Adura ti kaluku maa n gba ni pe ki omo re gbeyin wa ti a ba dagba, ti a ba dogbo, ohun to daju ni pe inu idunnu ati ayo ni mama to bi gbajumo olorin Islam nni, Alaaja Seidat Bashirat Ogubremi ti gbogbo aye mo si Iya-n-Ghana, iyen  Alaaja Mariam Abike Fiwakesin yoo wa bayii, inu mama to fi gbogbo ojo aye e se esin Olorun yoo dun  pe awon omo rere lo gbeyin oun.

Bii omi lawon eeyan ri lojo ti won sadura ojo kejo fun mama yii, eyi to waye niluu Agege, nipinle Eko. Bawon olorin islam se po nibe jaburata, bee lawon produsa awon olorin ko gbeyin, awon aafaa nla nla naa fi ojo naa ye Iya-n-Ghana si,eyi ti ko yo awon ololufe obinrin naa sile. 















No comments:

Post a Comment

Adbox