IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 13 July 2019

ALFA SEMIU LASTBORN, EEYAN WA DAADAA LO N SOJOOBI, GBOGBO WA PATA LA KI I KU ORIIRE

Gbogbo awa osise ileese Ojutole Online Media la ki eeyan wa daadaa, eeyan wa pataki, Alaaji Semiu Lastborn, oga agba leka igbokegbodo nileese Al-Hatyq Travel and Tours ku oriire ojoobi won to waye loni-in ti i se ojo kerinla, osu keje, odun 2019.

Adura wa ni pe komo olojoobi sopo odun laye ninu ola, owo, igbega, alaafia nla ati arisiiki to ga ju. Hapi Batide sir, igba odun,
iseju aaya ni. 

No comments:

Post a Comment

Adbox