IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 12 May 2019


Ilu Idiroko, nipinle Ogun mi titi lojo Jimo, Fraide to koja nibi ti ijo Istijaba duah ti Alaaji Ganiy Ajibade Akewusola je oludasile re se. 

Baba naa topo mo si Olorun nidahun si Adura gba awon eeyan pataki lawujo lalejo, ti oniwaasi agbaaye nni Sheik Saanu Shehu se waasi lojo naa.
Alaaji Ganiy Ajibade ni Fahharul Ulamoni ijo Tijaniyat ni Yewa, bee lo tun je Baba Adinni ijo Aponle Anobi to wa niluu  Ibadan, o si tun je polopo oye nidii esin islaamu kaakiri agbaye.
Awon oba alaye bii oba Ilashe Oba John Olaifa, Oba Idiroko, Oba John Olakunle, Oba Ijofin oba Moruf Ayinla wa nibe.
Bakan naa ni ore  timotimo  Alaaji Ajibade iyen Alaaji Razak Adeleke ati iyawo e naa wa nibe.
Awon olorin bii Saoty Arewa, Ere Asalatu, Mariam Akiki, Ahmad Alawiye atiyawo e, Alaaja Rukayat Alawiye naa wa nibe














No comments:

Post a Comment

Adbox