IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 13 May 2019

GBAJUGBAJA OLORIN EMI TAYE N FE, LANRE ATORISE SOJOOBI,GBOGBO AYE LO KI I KU ORIIRE

Lati bii ojo meta seyin lawon eeyan kari agbaaye ti n ba gbajumo olorin emi taye n fe nni, Dokita Olanrewaju Afolabi Teriba dupe lowo Olorun pe o tun le odun kan si i loke eepe, gbara tile aaro yii mo lawon eeyan ti n ba wolii Olorun alaaye naa sajoyo ojoobi ohun to n lo lowo bayii.

Gbogbo wa pata nileese Ojutole naa ba Atorise dupe lowo Olorun pe odun yii soju e, adura wa ni pe ko se opo odun laye ninu ola, owo,alaafia ati alubarika repete. Igba odun,iseju aaya ni.

No comments:

Post a Comment

Adbox