IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 24 May 2019

ILEESE AL-HATYQ TRAVEL AND TOURS LIMITED TI GBERA PELU AWON ONIBAARA WON LO SI UMRAH

Aaro yii nileese kan gboogi lara awon ileese to n ko awon eeyan lo si haji ati umrah, iyen 'Al-Hatyq Travel and Tours Limited' ti Otunba Wale Badmus je oga agba e gbera lati orile-ede yii pelu awon onibaara won lo si umrah odun yii.

Lati aaro kutukutu ni Otunba Badmus tawon mi-in tun mo si Wale Ticket pelu awon osise e ti Alaaji Semiu LastBorn saaju won ti wa ni papako ofunrunfu Murtala Muhammed to wa ni Ikeja lati ri i pe gbogbo awon onibaara yii ni won gbadun ara won daadaa, ki won too gbera lo si umrah.










Ojutole gbadura pe daadaa lawon onirin-ajo yii yoo de.

No comments:

Post a Comment

Adbox