IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 22 April 2019

OPE O: TOYIN AIMAKHU KO NI I PE E BIMO O

Ojutole fi da yin loju pe gbajugbaja osere tiata Yoruba nni, Toyin Aimakhu, ti loyun, osere omo bibi ilu Edo naa ko ni i pe e bimo. Gbogbo eni to ba ri foto obinrin naa lori eka ayelujara lenu ojo meta yii yoo mo pe kinni ohun ti kuro ni ohun ti eeyan yoo fowo bo, isu Oluwa naa ti ta jade daadaa.

Oserekunrin to fi ilu Abeokuta sebugbe la gbo pe Toyin loyun fun, o si dabii eni pe won ti so won po labenu gege bii toko-taya.

Fawon ti ko ba ranti daadaa mo, osere kan toruko re n je Adeniyi Johnson ni Toyin koko segbeyawo pelu e, sugbon ti aarin won pada daru.

Leyin ti Toyin ati Adeniyi ja, lobinrin naa pada sodo Seun Egbegbe to ti koko fe ri, ki aarin won tun too daru. J

u gbogbo  e lo, ojo ti ariwo e ku ewu omo yoo so nile awon Toyin la wa n reti bayii.
 

No comments:

Post a Comment

Adbox