IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 22 April 2019

O PARI: JUMOKE ONIBUREEDI, TI KO OKO E SILE PATAPATA

Iroyin to te wa lowo bayii  ni pe Olajumoke Orisaguna, omobinrin onibureedi to di ilu mo on ka orekelewa ti ko oko e sile. Ohun ti a gbo bayii ni pe omobinrin omo bibi ilu Iree, nipinle Osun ti yo oruko oko e kuro lara oruko re, Olajumoke Chris lo n pe ara re bayii.

Saaju asiko yii la gbo pe wahala ti koko sele laarin oun ati oko e, esun to fi kan Jumoke ni pe ko gboro soun lenu mo, o ni loruloru bii oro lo maa n wole, ti ko bikita foun gege bii oko mo.

Beeni Jumoke naa so pe ole lo n yo oko oun lenu, o lokunrin naa ko fee sise rara, ati pe alaimoore eeyan kan bayii.


No comments:

Post a Comment

Adbox