IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 4 April 2019

ONI LOJOOBI SHEU JAMIU AMIOLOHUN, E JE KA KI WON KU ORIIRE

Gbogbo wa pata la ki nileese Ojutole la ki baba wa daadaa, Sheik Jamius Sanusi Amiolohun ku oriire ayeye ojoobi won to waye loni-in. Adura wa ni pe ki baba se opo odun laye ninu ola,owo, alaaafia ati alubarika nla.
Igba odun,iseju aaya ni sir.

No comments:

Post a Comment

Adbox