IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 23 April 2019

E WO OMOBINRIN YII, OUN LOBINRIN TO GA JU NIGBORO EKO

Omobinrin ti e n wo yii, Yvonne Rofem loruko e, oun ni won so pe o ga ju nigboro Eko, iwon ese bata mefa ati die ni. E o ri pe onise ara ni Olorun, bo se da eni kukuru, bee lo da eni gigun. E je ka jo gbe Olorun tobi  

No comments:

Post a Comment

Adbox