IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 8 October 2018

OPE O: GBAJUMO AAFAA ONIWAASI NNI, SHEIK HAMMED ALFULANNY RA MOTO OLOWO NLA

Inu idunnu ati ayo ni gbajugbaja aafaa oniwaasi nni, Sheik Hammed Alfulanny Olanrewaju, wa bayii. Ohun to fa idunnu ohun ni pe okunrin naa sese ra moto olowo nla ni.

Ninu oro e lo ti so pe oun dupe lowo Olorun fun oore ayo to se fun oun yii. Awa naa nileese Ojutole ba Sheik  dupe lowo Olorun, Olorun yoo tunbo se opolopo oore fun won.




No comments:

Post a Comment

Adbox