Ojoobi se pataki laye eda, ojo nla ti gbogbo aye maa n ki eeyan ku oriire ni. Bee gele lo ri fun eeyan wa daadaa, Arabinrin Olayinka Ogunleye Oke-Eko, anaa layeye ojoobi e, gbogbo aye ni won ki i ku oriire.Awa naa nileese Ojutole ba eni wa yii sajoyo ojoobi e, a gba a ladura fun un pe opo odun ni yoo se laye ninu ola,owo, alaafia ati igbega nla. Igba odun,
iseju aaya ni.

No comments:
Post a Comment