Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki baba wa daadaa ati alatileyin wa, Sheik Alaaji Muhammed Saheed Babatunde ti gbogbo aye mo si Oluomo Kutonu ku oriire ayeye ojoobi won to waye loni-in.
Adura wa ni pe ki Owo Baba Olayinka sopo odun laye ninu ola, owo, alaafia ati a i ku ti i se baale oro. Ki Olorun ma fi ku to yawo pa yin, e o si ni i dero eyin
laelae. Igba odun, iseju aaya ni.
Tuesday, 9 October 2018
ONI LOJOOBI OLUOMO KUTONU,GBOGBO WA LA KI BABA OLAYINKA KU ORIIRE
Tags
# ORO TO N LO
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
ORO TO N LO
Tags
ORO TO N LO
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment