Aaro oni-in ni won sinkuu, Alaaja Aminat Akanni Onikijipa, ti i se mama to bi aafaa nla nni, Sheik Faruq Onikijipa, siluu Ilorin, ti i se ilu abinibi e .Awon aafaa nla nla atawon afenifere ni won peju-pese lati ba sheik nla yii sin mama e. Aaro ana ni mama yii jade laye le

ni aadorun-un odun.

No comments:
Post a Comment