Awon to sunmo Sheu nla yii so pe ki i fi mama to ku yii sere, ife nla ni won so pe o wa laarin won, gbogbo ohun tomo maa n se fun mama e la gbo pe Sheik se fun mama won kolojo too de.
Ojutole naa ba Sheik Faruq daro iku mama won, ki Olorun fori ji won, ko duro ti awon mama fi sile lo
No comments:
Post a Comment