Arabinrin J.O Sadare, ti i se oga ileewe girama Isolo Senior Secondary School to wa niluu Isolo, nipinle Eko la gbo pe o ti le awon akekoo obinrin marun-un danu, lori esun pe won n wo ijaabu wa sileewe.
Lori ila,lasiko tawon akekoo gbogbo wa nileewe logaa ileewe yii kede pe oun ti le awon omoleewe naa. Sugbon awon akekoo yii ti won je musulumi ko lo sile won, dipo bee Keke Napep kan to wa nitosi ileewe won ni won so di yara ikawee, ibe ni won ti kawee won.
No comments:
Post a Comment