IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 7 September 2018

SAT GURUMARAJ J TU ASIRI ASO PUPA ATI ODODO [FLOWER} TO N LO

Oludasile ijo 'One Love Family', Sat Gurumaharaj .j ti tu asiiri aso pupa (red cloth) ati ododo (flower) ti won n lo ninu ijo e. 

Lasiko to n ba Ojutole soro, Sat Gurumahara j so pe gbogbo aye lo mo pe ife ati alaafia laso pupa ati ododo  je. 'Eyin naa e wo o, ti won ba fee se odun ayajo awon ololufe, aso pupa ni won maa n wo, ti ololufe meji ba fe fee fi ife han si ara won fulawa ni won maa n fun ara won. 

Ife ati alaafia lo se pataki lodo wa, ohun ti aso pupa ati fulawa ti  a n lo tumo si niyen. Ori ife la gbe gbogbo ohun ti a n se lodo wa le lori, ife lo se pataki lodo wa, ohun ti a fe ko joba kari aye niyen'

.  

No comments:

Post a Comment

Adbox