Iroyin to te wa lowo bayii ni pe ondije ipo aare ninu egbe PDP, Alaaji Ibraheem Shek
arau ti pada sinu egbe APC, okunrin naa ti kuro ninu egbe PDP to wa tele. Aaro oni lokunrin naa sepade pelu alaga gboogboo egbe egbe APC, Adams Oshiomhole, niluu Kano.
Ninu oro Shekarau lo ti so pe oun gbe igbese naa nitori boro oselu orile-ede yii se ri. Bee lo so pe oun foro naa to awon eeyan oun leti, koun too pada sinu egbe APC. Gomina ipinle Kano, Abdulahi Ganduje naa wa nibi ipade yii.
No comments:
Post a Comment