Kayeefi nla niku omokunrin kan toruko re n je Prince Daniel je fun gbogbo awon to gbo nipa iku ojiji tomokunrin to kawe jade nilewe 'Isaac Jasper Boro College of Education' to wa ni Sagbama, nipinle Bayelsa naa fi pa ara e.
Gege bi a se gbo, won nitori afesona e so pe oun ko se mo, to si ba okunrin naa mi-in lo lo fa a ti Daniel fi gbe majele je,ti kinni ohun si gbemi e.
Ohun to tunbo ba awon eeyan ninu je lori iku ti Daniel fi pa ara re ni pe oun nikan lomokunrin ti baba e bi
Bakan naa la gbo pe won ti sinku e siluu Kaima,nipinle Kwara ti i se ilu abi
No comments:
Post a Comment