Ojo kejidinlogun, osu kokanla, larewa osere tiata Yoruba nni, Ranti Adetunji, yoo ko fiimu e tuntun to pe ni 'Itunu Ife' jade bii omo tuntun. Gbongan 'Eko Club' to wa ni Surulere, niluu Eko layeye naa yoo ti waye.
Gbajugbaja osere fuji nni, Alaaji Sule Alao Malaika ti gbogbo aye mo si Madiba tabi Quibla fuji ni yoo saaju awon olorin bii: Small Doctor, Yomi Sars, Bossy B, Skally Mental, Alonso, Shoki Apala, Destiny Fuji, Olumide Mawe ati FM Aminatu korin lojo naa.
Lasiko to n ba wa soro nipa ayeye yii, Ranti so pe gbogbo awon ololufe oun pata ni won yoo gbadun ara won lojo ayeye yii. Bakan lo ro won pe ki won fi ojo naa ye oun si.
ANKARA TAWON EEYAN YOO FI WOLE REE |
No comments:
Post a Comment