Gbogbo awon eeyan ti won ti wo fidio yii ni won so pe ise nla,ise olopolo ni Alfa-mi-ni se sinue .
Lati tunbo je ki alaafia joba kari aye, gbajumo aafaa oniwaasi, to tun n korin, Sheik Khalifa Ismael Aderemi ti gbogbo aye mo si Alfa-mi-ni ti gbe fidio orin 'Oju Orun' jade .
Fidio naa ti won ya lorilede Saudi ni aafaa nla yii ti salaye gbogbo ona ti Olorun fi ta ko ija esin ninu alukuraani, bee lo gba gbogbo awon eeyan nimoran pe ki won gba alaafia laaye,
nitori pe Olorun ko feran ija esin rara.
Gbogbo awon eeyan ti won ti wo fidio yii ni won so pe ise nla,ise olopolo ni Alfa-mi-ni se sinue .
Gbogbo awon eeyan ti won ti wo fidio yii ni won so pe ise nla,ise olopolo ni Alfa-mi-ni se sinue .
No comments:
Post a Comment