IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 5 September 2018

OPE O:GBAJUGBAJA AAFAA ATI OLORIN, ALFA -MI-NI TI DE LATI MEKA

Afi idunnu atayo so fun gbogbo eyin ololufe gbajugba aafaa oniwaasi, to tun n korin, Sheik Ismael Aderemi Alkhalifa tawon eeyan mo si Alfa-mi- ni pe okunrin naa ti de lati ilu Saudi to lo fun hajji odun yii. 

Ninu oro e lo ti so bayii pe ' A lo si Meka loruko Olorun Alaanu, a si dupe lowo e pe o so wa pada sile layo. Olorun o seun'

1 comment:

  1. Ope ni fun olohun to so wo lo to tun so wo pada,Alhamdullah

    ReplyDelete

Adbox