IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 5 September 2018

Ẹgbẹ ADP ni yoo jawe olubori nipinlẹ Ogun lọdun to n bọ- Wale Egunleti

Bi wọn ba sọ pe ẹgbẹ oṣelu wo lo tun rinlẹ kaakiri ipinl Ogun bayii, ti wọn tun ti wa ni imurasilẹ fun idibo tọdun to n bọ nipinlẹ Ogun, Won ko ni tii darukọ ki wọn to sọ pe ẹgbẹ oṣelu ADP ni.  Bo tilẹ jẹ pe ko tii  ju ọdun kan lọ, ti wọn da ẹgbẹ naa silẹ  sibẹ ṣe lo n figagbaga pẹlu awọn ti wọn ti wa nibẹ tẹlẹ lo. Idi niyii tawọn kan fi sọ pe bii nnkan ṣe n lọọ yii, o ṣe e ṣe ko jẹ pe ẹgbẹ naa ni yoo rọwọ mu.
Laipẹ yii ni alaga ẹgbẹ naa, Oloye Wale Egunleti ṣe ifọrọwerọ pelu oniroyin wa nipa bi wọn ṣe da ẹgbẹ naa silẹ, ibi ti wọn ba a de ati imurasilẹ wọn fun ibo gomina atawọn ipo yooku, ti yoo waye lọdun 2019. Ohun ti alaga naa ba wa sọ ree
Ohun to mu wa da ẹgbẹ naa silẹ.
Ẹ ṣe pupo, loootọ bi a ba ni ka woo yoo ti le ni ọdun kan ta a da ẹgbẹ ADP silẹ, ohun ta a le sọ pe o mu ki a da ẹgbẹ naa silẹ ko jinna rara, bi ẹyin oniroyin naa ba woo ilu le, ko fararọ inu awọn eeyan ko dun, iya n jẹ wọn, awọn to si wa nidi agbara, o dabi pe emi o gba tiẹ, iwọ ko gba temi ni wọn n ba kaakiri.
Owo Naijiria ni gbogbo wọn n le kaakiri, wọn ti gbagbe pe wọn dibo fun wọn ki wọn lọọ sibẹ lati ṣoju araalu lati mọ bi nnkan yoo ṣe dara fawọn mẹkunnu, nigba tawa bẹrẹ si ni i wo, aa ri i pe awọn eeyan n pariwo pe inu inira lawọn wa yii, ti ko si ifọkanbalẹ kankan fawọn, idi niyi tawọn eeyan kan fi jokoo fun idasilẹ ẹgbẹ tuntun.
Bi ẹ ba lọọ wo iwe ofin ẹgbẹ wa, ẹ o ri i pe o yatọ si eyi ti wọn ti n ba a bọ tẹlẹ, idi niyi ti wn fi s pe awn le j m gb naa tl o ugbn ki awn wa gb mi in ti yoo gba awn mkunnu sil lw inira tawn jgudujra oloelu n ko wn si i.
Awn ti le bawn wa ninu gb naa ri tl ugbn awn gbd wa na mi in ti yoo gba yat si tl, nitori gbogbo ibi ti wn ba iṣẹ ibaj yii ti to g. Eyi lo si faa ti wn fi n bawn eeyan sr, bo til j pe yoo oro fun wn lati gba wn gb.
p wn lo n sr nipa awn d, awn abarapa atawn omode,ipo ti wọn wa ko tẹ wa lọrun, ọpọ wọn ni ko niṣẹ. A o ri i pe wn fiya j wn ju, to ba j ileewe ijba dara ni, awn araalu ko nii maa mu m wn l sileewe aladaani, to ba si maa wa, awn olowo gidi ni wn yoo maa l. Wn ti ba eto k j patapata. Idasil gb wa wa fun yiyi igba pada fawn araalu.
Ẹgbẹ to darapọ mọ ADP ki i ṣe PDP nikan
Emi naa gb pe wn ni awn to kuro ninu gb oelu PDP lo wa ni ADP, ir to jinna si oot ni, mo f k m pe ni to j alaga gb naa lapap niluu Abuja, iyn Alaaji Yabag Yusuf Sani, emi ko gburo ri ninu oelu, looot ni wn pe awn bii Baba wa, Alani Bankle ti wn j alaga igbim agba fgb naa.
Baba Bankole yii plu awn to k iwe ofin fgb oelu PDP,o si tun plu awn to k APP laye jun. Awn eeyan to wa ninu wa nibi, awn ara igberiko ni wn, ko si agbowo rin ninu wa, ohun taw a n s fun wn ni pe a f ki wn ejba ara wn, bi wn ba yan kansel, o gbd j ni ti yoo maa m nnkan to lọọ ni wọọdu , bẹẹ gl awn oye oelu yooku.r owo yii naa ni ioro wn, epo yii naa si ni. Ko sni to n wyin wo m ninu wn ti wọn ba depo naa tan.
Gbogbo awn nnkan wnyii la a gbd fopin si, awa kan la a si ni lati br . ni kan lo s fun wa pe nu yin oloelu dun, mo ni bẹẹni, ugbn beeyan ko ba a ra ir ko le ri oot ra.
Ki i e nitori Alani Bankle la e da gb ADP sil
Awn kan maa n s pe nitori Baba Alani Bankle la e da gb ADP sil tabi pe awn lo ni, r ko ri bẹẹ, mo s tl pe awn kan wa to j pe iubu gb ni wn yoo maa wa, ki lo buru ju bi Baba Bankle ba n e gb kan, tm r naa n e.
e gbogbo awn to wa ninu gb wa, e bi Bankle ni wn, to ba ti j pe gb wn ni, e awn lo maa e gomina, lo maa e snet, lo maa e narebu, e awn naa ni, emi o ro pe o y kawn eeyan maa s nnkan ti ko nitum.
Ati pe ẹgb yii ki i e tipinl Ogun nikan, gbogbo ipinl lo wa, bi nikan ba wa n e daadaa, awa le maa fẹran r, tabi ri oju , ero wọn ni pe awn ko nii jẹ kiru onitọhun gbe apoti, to ba si gbe apoti, ti gb ba ro pe oun lo le yanju ioro to wa nilẹ, awọn ko nii fun un ṣe wọn ti gbagbe pe Ọlọrun ju ẹda lọ.  
Bo tiẹ jẹ pe awọn lo daa silẹ gẹgẹ bi wọn ṣe sọ, ko si nnkan to buru nib. Eyi to j awa logun ni pe e awn to fẹẹ dije yii, e ki i e awn ti yoo tun dakun ioro wa, a n f iyipada to muna doko, ki i e iyipada si laburu, r pe Bankle lo da gb sil k lo kan wa bayii.
Ilara ni Amosun fi le wa kuro ni skiteriati ta a wa tl
Lojiji lawa naa gb pe Amosun atawn eeyan ni ki wn wo skiteriati ta n lo gg bi fiisi to wa ninu Ibara Housing, awa ko m nnkan to ṣẹl. Ki awa naa to gba fiisi to wo naa, a kk woo yika pe awn fiisi to wa lagbegbe, a ri i pe eyi to bojumu tawn ileee nlanla naa wa nibẹ to si ba ode oni mu, iyn la wa ro, ta a fi ni kawa naa maa lo sib.
Latigba ta a ti de b, jj wa la a n l, a ko l ba eeyan ja, bẹẹ la ko da wahala sil, a fi bi wn e de ti wn s pe ib ko bofinmu, awa ko si fẹẹ fa wahala, nitori la e wa ibo mi in laim pe lrun ti fr naa e ile ba to jo, wa lo bu sii.
Nnkan tawa ri ninu r naa ni pe wn fẹẹ maa fin wa lran ni, ati pe wn n jowu wa, wn ti ri w tawn eeyan ba wọnu gb naa,  gbogbo ẹ lo n jawọn laya, o ti di nnkan ti wn ko lero, idi niyi ti wn fi ti ilara b.
Awa ko ri ti egbe ADC Obasanjo ro nipinlẹ Ogun
Loju tiwa, awa ko ri gb ADC, basanj ro gg bii alatako, nitori nnkan ti Baba s ni pe tawn ba ti da gb sil tan, awn a yw nib. Awa wa nibi ta a n is wa l, nnkan temi kan ri ni pe ADC  ati ADP ti fẹẹ j ara wn, awn mi in ti fẹẹ maa gbe fun ara wn, awa o si fẹẹ ba nikni ro j.
Awa etan lati iṣẹ p plu gb oelu mi in
Bẹẹni, a etan, iyn gb oelu ti ajọṣe wa fun araalu yoo dgba.Ti ki i e pe wn kan fẹẹ maa kowo sinu gb, a fẹẹ jokoo ka wo nnkan to n dun awn eeyan lkan, nnkan ti wn n f, ki ara le tu awn araalu, ohun ta da gb yii sil fun niyn.
Ijoba Amosun loju temi
Loju temi o, ko sni to wa sib lati wa ba ilu j.Nnkan tijba ba lagbara lati maa e, ko maa e e. Ṣọja l, ṣọja b nijba, bi nikan ba de yoo e iwn to le e, ugbn mo nigbagb pe fun ilsiwaju ipinl ati orileede, o y ki ipade laarin araalu ati ijba maa waye loorekoore.
Nnkan kan ti mo m to si n j dun kan fun mi ni pe o y ki a maa woye pe bawo la e fẹẹ j ki ipinl ati orileede ri laarin ogun dun. O y ki wn ni eto pataki bawn nnkan yoo e ri fj iwaju, ti ijba kan ba ti de ti ko pari , ijba to ba wle lyin yoo tsiwaju nibi to ba a de. Awa sin awn araalu ni ki i e pe ki nikan de b, ko maa e nnkan to wuu.
Aye wa fun Kashamu lati darapo m wa
Ko si nnkan to buru ti Buruji Kashamu ba s pe gb wa wu oun lati darap, ko maa b, a maa fi tay gba a koda nikni to ba wuu ni ore f wa fun un lati darap m wa ugbn sa, o gbd tle ilana ati ofin ta a fi da gb yii sil. To ba ti faram nnkan ti iwe ofin ati ilana ADP s, iyooku kere.
Bakan naa, to ba ti moju kuro ninu gbogbo ratirati ti wn n ba b tl ninu gb ti wn wa tl, aa ṣetan lati ba a iṣẹ papọ, niwngba to j pe gb oelu Naijiria ni.Lara ni pe ti wn ba fun un ni tikti to wle, o gbd wa maa y awn eeyan to n oju wo, o si gbd m pe ko nii maa foju gb ri rdrd tabi koun naa maa owo ilu baubau.
Eto abo mh lorileede yii
Bi a ba ni ka s tododo, eto abo mh ni orileede wa, lrun nikan ni ko saanu wa. Aar wa ni ki a bẹ, ki wn foju rere wo awn mkunnu, ki wn wa ojutu si bawn Fulani darandaran e n pa awn eeyan bii ni pa ran, bẹẹ ni ki wn tun iṣẹ lori awn ajinnigbe.  Inu lrun ko dun si ki a maa pa eeyan.
ADP ko iṣẹ fun Dimeji Bankole lati di gomina o
Iskus lawn to n s pe nitori ki Dimeji Bankle le di gomina ni gb ADP e n iṣẹ ta a n e yii, ko si oot nib, awa ati Dimeji ti j wa pap, o ti le ni dun marun un, ti a j n iṣẹ l, a j wa ninu gb yii naa ni, nnkan to dara ni lati maa ba eeyan rere rin.Ki i e ni ti ko ni nnkan e gbogbo wa j n iṣẹ pap, nikni to ba wuu ninu gb lo le dije fun ipo gomina, gbogbo iyooku ti wn n s yn, aheso lasan ni.
Awa o pin ipo gomina si ya kankan
Iwe ofin wa nipinl Ogun ati ti gb wa ko ti i s pe wn ti n pin ipo gomina ni ya kan si omi in, ohun tawa duro lori ni pe ibikibi lni to ba nifẹẹ lati jade, ti le jade wa, lyin naa la maa e pamari, ohun ni yoo s ni ti yoo oju wa. Bi awn m gb ba bilifu ni ti wn roo pe o le e nnkan ti wn n fẹẹ ti ko si nii doju ti wn, oun ni wn yoo dibo fun un. Emi ro pe nnkan to dara niyn, ki i e pe boya gba, Yewa tabi Ijbu lo gbd oju wa. Gbogbo wa lo t si.
A ti bẹrẹ irinajo kaakiri ipinl Ogun
Ls to kja lhun la a ti br irinajo sawn ijba ibil Ogun to wa nipinl wa, idi ta fi n e bẹẹ ni lati bawn m gb wa sr, a tun fẹẹ m ibi ti nnkan de ati lati gbaradi fun ibo to n b ldun 2019. B
...

No comments:

Post a Comment

Adbox